Info
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma...
show more
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma ṣe àfihàn àwọn Akéwí àti Olùkọ̀tàn Yorùbá nílẹ̀ yí àti lókè òkun. A yóò ma ka ìtàn ní àkàgbádùn, bẹ́ẹ̀ lọmọ ṣorí fún ewì lédè Yorùbá, tí a yóò sì ma fi eré orí-ìtàgé ní kíkà dára ya.
show less
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ
11 JUL 2020 · Ètò yí ni àkọ́kọ́ṣe lórí ìkànnì yí , ohun tí a gbé ètò yí kalẹ̀ fún ní láti máa ṣe ìgbélárugẹ̀ fún ewì alohùn Yorùbá àti kíkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú. Ètò alẹ́ èní ń ṣe àfihàn ìgbéjáde ewì alohùn ÒGÚLÚǸTU láti ọwọ́ọ Ìgè Àdùbí.
Ìgè Àdùbí
Atọ́kùn ètò
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma...
show more
ÀRÒFỌ̀ AKÉWÌ jẹ́ ètò àtàtà èyí tó ń buyì kún Àṣà àti ìṣe ẹ̀yà Yorùbá nípa gbígbárùkù ti ìgbega fún ewì àti ọ̀rọ̀ àtẹnudẹ́nu ẹ̀yà Yorùbá. Ètò yíí yóò ma ṣe àfihàn àwọn Akéwí àti Olùkọ̀tàn Yorùbá nílẹ̀ yí àti lókè òkun. A yóò ma ka ìtàn ní àkàgbádùn, bẹ́ẹ̀ lọmọ ṣorí fún ewì lédè Yorùbá, tí a yóò sì ma fi eré orí-ìtàgé ní kíkà dára ya.
show less
Information
Author | AROKO ONLINE RADIO |
Organization | AROKO ONLINE RADIO |
Categories | Arts |
Website | - |
- |
Copyright 2024 - Spreaker Inc. an iHeartMedia Company